Jss1 Yoruba third term exam
  • 1. Ni ile yoruba 6am--11am is
A) Owuro
B) Ale
C) Idaji
D) Oru
  • 2. 2am- 4am is
A) Iyaleta
B) Ale
C) Osan
D) Aajin
  • 3. Yoruba ni kiki fun awon igba yi ayafi
A) Ojo
B) Isele
C) Asiko
D) Oro
  • 4. "E ku ireju "wa fun
A) Someone eating
B) Someone sleeping
C) Someone fighting
D) Someone relaxing
  • 5. Eku ayeye"
A) For hot weather
B) For farmer
C) For party
D) For someone who farts
  • 6. Se aayan ogbufo oro yii: "culture"
A) Asa
B) Esin
C) Iwa
D) Ore
  • 7. Stage
A) Aja
B) Ori itage
C) Ori pepe
D) Ori apata
  • 8. Competition
A) Apara
B) Idije
C) Asayan
D) Iwadi
  • 9. Joke
A) Asa
B) Iwa
C) Esin
D) Apara
  • 10. He was ashamed of his behavior
A) Iwa re da
B) Oju ti nitori iwa re
C) Ona ara re nitori iwa re
D) Oju re da
  • 11. Aayan ogbufo ni
A) Pipa ede kan re
B) Kiko ede kan
C) Lilo ede kan
D) Tutu ede kan si omiran
  • 12. Aso wa fun
A) Fifi nu le
B) Bibo asiri ara eni
C) Fi fa ya
D) Sise afihan ara eni
  • 13. Aso wiwo pin si ona________
A) Meta
B) Meji
C) Merin in
D) Marun un
  • 14. E wo ni ki se aso obinrin
A) Dandogo
B) Buba
C) Gele
D) Iro
  • 15. E wo ni kii se Aso ode oni
A) Tai
B) Gbariye
C) Seeti
D) Kotu
  • 16. So oruko awon eranko wonyii ni ede yoruba: "Owl"
A) Owiwi
B) Ikoko
C) Igbin
D) Aja
  • 17. Cobra
A) Igala
B) Sebe
C) Obo
D) Aparo
  • 18. Peacock
A) Asa
B) Ogongo
C) Okin
D) Igun
  • 19. Bedbug
A) Okin
B) Idun
C) Idin
D) Eliri
  • 20. Gbolohun to ni eyo oro ise kan ni
A) Gbolohun afarahe
B) Gbolohun to gbajumo
C) Gbolohun abode
D) Gblohun onisekan
  • 21. Gbolohun _______ ni oni oro afarahe
A) Gbolohun abode
B) Gbolohun onibo
C) Gbolohun gbajumo
D) Gbolohun onisekan
  • 22. Bola fo aso, apeere gbolohun
A) Gbajumo
B) Abode
C) Onisekan
D) Onibo
  • 23. Mo pe sugbon ko gbo,
A) Golohun onisekan
B) Gbolohun olowo
C) Gbolohun abode
D) Gbolohun alakanpo
  • 24. Ki ni oro afarahe inu gbolohun yii: "Aso ti mo ra ti fa ya
A) Ra ti fa
B) Ti mo ra
C) Aso
D) Fa ya
  • 25. Ko awon onka yii ni ede Yoruba : 300
A) Egbeta
B) Oko
C) Igba
D) Oodunrun
  • 26. 600
A) Ogofa
B) Eedegbeta
C) Egbeta
D) Aadofa
  • 27. 400
A) Ogoji
B) Aadorin
C) Irinwo
D) Ogorin
  • 28. 1000
A) Egbewa
B) Ogowa
C) Egberun
D) Aadowa
  • 29. 500
A) Eedegbeta
B) Ogorun
C) Marun le lodo
D) Aadorun
  • 30. Okan lara Awon ise ti won ma n ran ra won lowo laye ati jo ni
A) Ounje sise
B) Omi pipon
C) Aso fifo
D) Ile kiko
  • 31. Asa iran ara eni lowo je ki ise
A) Tete ma pari
B) Won
C) Pe
D) Baje
  • 32. Agbe le ti ipase iran ara eni lowo di
A) Olojukokoro
B) Olosi
C) Olowo repete
D) Ole
  • 33. Okan ninu awon yii ni a n gba ran ara eni lowo
A) Ija
B) Ajo
C) Eke
D) Awin
  • 34. Eni be owe gbodo pese
A) Ile
B) Owo
C) Aso
D) Ounje
  • 35. Oruko miran fun alafowosowopo ni
A) Alamojuto
B) Alajetan
C) Alajeseku
D) Alayanjuran
  • 36. Egbe alafowosowopo fi anfaani
A) Lati yaa ilopo meji owo ti o da
B) Lati yaa owo lai dawo si nu egbe
C) Lati ma da owo pada mo
D) Lati da owo pada nigba ti o ba wu e
  • 37. ______ ni oba ile ife
A) AKire
B) Olowo
C) Ooni
D) Timi
  • 38. _______ ni oba Ibadan
A) Onibadan
B) Alasebadan
C) Olubadan
D) Olowobadan
  • 39. Bawo la se n ki "Oba"
A) Ki idi le mo aga
B) Ke se ko je bata
C) Ki ileke o kan ile
D) Ka de o pe lo ri
  • 40. Pari ori yii: "ore relarela kii________
A) Pe re ja
B) Pe lowo
C) Pe lo si ilu oyinbo
D) Pe bimo
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.