Ede Yoruba Jss2: 2nd term Exam
  • 1. 1. Paari Orin yii " Omo to mo iya re loju o" ________
A) Iwa rere lo Wu yen
B) Olowo ni no di ola
C) Osi yo ta Omo yen pa
D) Inu re Yi o ma dun ni
  • 2. 2. Lara iwulo Orin ni ___________
A) A Le Fi ya owo
B) A Le Fi tan eniyan je
C) Kiko ni Leko omoluabi
D) Kiko ni ni eebu
  • 3. 3. Okan ninu awon elo Ogun ni
A) Sibi
B) Igbale
C) Ofa
D) Okun
  • 4. 4. A Le dekun Ogun pelu awon Ona wonyi ayafi
A) Ife
B) Nini Emi idariji
C) Ikorira
D) Iwapele
  • 5. 5. _______ ni wiwa ni ifokanbale ti ko si Ogun
A) Ijakadii
B) Orikunkun
C) Alaafia
D) Ibinu
  • 6. 6. Ogun Le sele nipa _____
A) Bi bowo fun Ara eni
B) nini ife Ara eni
C) Fifun ni ni eto ani
D) Gbigba iyawo oniyawo
  • 7. 7. ...... Ki ni Oro ise Inu gbolohun yii " mo ka iwe
A) Mo ka
B) Mo
C) Ka
D) Iwe
  • 8. 8. O wa........ko ba mi, Oro asopo wo ni o to lati lo?
A) Nitori
B) Nigba ti
C) Sugbon
D) Ati
E) Pelu
  • 9. 9. Apeere Oro aropo oruko ni
A) Mo
B) Jade
C) Tola
D) Dudu
  • 10. 10. Tobi fo aso," fo " je
A) Oro asopo
B) Oro afarajo oruko
C) Oro ise
D) Oro oruko
  • 11. 10. Opomulero inu gbolohun ni,.....,
A) Oro oruko
B) Oro atokun
C) Oro aropo oruko
D) Oro ise
E) Oro apejuwe
  • 12. Aso funfun ni mo wo, "funfun" je
A) Oro asopo
B) Oro ise
C) Oro apejuwe
D) Oro oruko
  • 13. 12. Igi naa ga fiofio, "fiofio je
A) Oro afarajoruko
B) Oro oruko
C) Oro asopo
D) Oro aponle
  • 14. 13.ninu ewi "Eko Ile", Eko ile _______
A) Buru pupo
B) Le fa ija
C) Ko ni iwulo
D) Se pataki
  • 15. 14. Eko ______ ni Eko ile
A) Arrugbo
B) Ode oni
C) Omo ikose
D) Adayeba
  • 16. 15 Omo to Ko ba leko Ile ,Ko Le _____
A) Begbe mu
B) Eesu
C) Lowo
D) Ja
E) Mowe
  • 17. 16. Emi ni oga won , "Emi ni je
A) Oro ise
B) Oro asopo
C) Oro aropo afarajoruko
D) Oko won wa leti odo
E) Oro oruko
  • 18. 17. Oro ti a n lo dipo Oro oruko ni oro.....
A) apejuwe
B) ise
C) aropo-oruko
D) atokun
E) asopo
  • 19. 18. Oro ti a fi n so oro meji po ninu gbolohun ni oro......
A) eyan
B) asopo
C) ise
D) abo
E) atokun
  • 20. 19. Ewo ni oro oruko ninu gbolohun yii 'Ronke se obe egusi '
A) Ronke
B) Je
C) Obe
D) Egusi
E) Se
  • 21. 20. 70 ni onka Yoruba je
A) Aadofa
B) Aadoje
C) Aadorun
D) Aadowa
E) Aadorin
  • 22. 21. Omolewa pupa foo, foo ninu gbolohun yii ni oro
A) Apejuwe
B) Alabode
C) Ise
D) Atokun
E) Eyan
  • 23. 22. Ki ni batani ihun oro yii KF duro fun ?
A) Konsonanti + Faweeli
B) Konsonanti + Faweeli + Konsonanti
C) Faweeli + Faweeli
D) Konsonanti + konsonanti
E) Faweeli + Konsonanti
  • 24. 23. Aadofa ni figo je
A) 210
B) 90
C) 109
D) 110
E) 320
  • 25. 24.kiko " Aiya " ni akoto ode oni ni
A) Aaya
B) Ayaa
C) Aeya
D) Aya
  • 26. 25." Papa" ni akoto ode oni ni
A) Paapaa
B) Papaa
C) Paapa
D) Papapa
  • 27. 26. Ninu Ewi "Iwulo Eko, iwulo Eko o _____
A) Da
B) Se koko
C) O ni itunmo
D) Legbe
  • 28. 27. Silebu melo ni o wa ninu oro yii 'olongbo' ?
A) Marun
B) Mefa
C) Meji
D) Merin
E) Meje
  • 29. 27. 250 + 250 = ?, ni onka Yoruba
A) Egbeta
B) Eedegberin
C) Eedegberin
D) Egberin
E) Eedegbeta
  • 30. 28. Iye Silebu melo ni gogogongo
A) Mefa
B) Marun
C) Meji
D) Mejo
  • 31. 29. Eko wulo ju Ile Kiko lo
A) Beeni
B) Beeko
C) Iro ni
D) Mi o mo
  • 32. 30. Eko n so ni di ____
A) Ole
B) Ogorun
C) Arugbo
D) Were
E) Ilumoka
  • 33. ______ ni afo ti afi ohun didun Ko, ti osi dun Ko sita
A) Ija
B) Ariwo
C) Orin
D) Asa
  • 34. Orin igbeyawo he Orin ti won fin Ko awon ______ logbon
A) Omode
B) Olomoge
C) Arugbo
D) Agbalagba
  • 35. Orin igbeyawo tun je ki obinrin mo _____
A) Awon ale oko e
B) Ojuse Nile oko
C) Mo eebu bu
D) Mo ijo jo
  • 36. Orisi Orin ni iwonyi ayafi
A) Orin igbeyawo
B) Orin eremode
C) Orin Eko Iwa rere
D) Orin onje jije
  • 37. Apeere Orin Iwa rere ni
A) Tani ba mi lo mo wi o, adendekun dekun o
B) Omo to moya re loju o
C) Baba mo n lo, iya mo n lo
D) Ibi olomo ba n re, ka di Jo lo
  • 38. Orin ikomojade je ka mo pataki
A) Ile kiko
B) Omo bibi
C) Iro pipa
D) Ijakadi
  • 39. Orin wulo fun
A) Ija eyameya
B) Gbigbe asa laruge
C) Fifa asa wale
D) Ebu bibu
  • 40. Orin Eko Iwa mu ki
A) Omode mo ijaja
B) Omode mo Iwa toto
C) Agbalagba ma re omode je
  • 41. Orin iremolekun mu ki omode ____
A) Ma gbe
B) Dake ekun
C) Maa tobi si
D) maa sunkun ni gbogb igba
  • 42. Lailai ni ode oni ni
A) Laelae
B) Laelaa
C) Loiloi
D) Laalaa
  • 43. Agadagodo je Oro onihun
A) Ffkfkfn
B) Fnkfkfn
C) Fkfkfkfkf
D) Kfnkfnkf
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — a math test site for students of all grade levels.