- 1. Mélòó ni álífábẹ̀ẹ̀tì konsonanti èdè Yorùbá?
A) 20 B) 15 C) 11 D) 18
- 2. 2000 ní òǹkà Yorùbá ni____
A) Ọgbọ̀n B) Ogójì C) Ẹgbẹ̀waa D) Egbèje
- 3. _____ni orísirísi ọ̀rọ̀ tí à ń lò nínú gbólóhùn
A) òwe B) Ìsòrí ọ̀rọ̀ C) gbólóhùn D) ewì
- 4. Ọ̀rọ̀ tó ń ṣiṣẹ́ Olùwà,àbọ̀, àti ẹ̀yán nínú gbólóhùn èdè Yorùbá ni___
A) Ọ̀rọ̀ àpónlé B) Ọ̀rọ̀ orúkọ C) Ọ̀rọ̀ ìṣe D) Ọ̀rọ̀ àpèjúwe
- 5. Ojú àti imú ń dùn mi. Èwo ni ọ̀rọ̀ àsopọ nínú gbólóhùn yìí?
A) àti B) imú C) oju D) dùn
- 6. Ọnà mélòó ni álífábẹ̀ẹ̀tì èdè Yorùbá pín sí?
A) Méjì B) Márùn-ún C) Mẹ́ta D) Mẹ́rin
- 7. Lẹ́tà fáwẹ̀lì èdè Yorùbá ni_____
A) b,d,g,gb,j,k,m B) a,m,n,y,j,t C) a,e,ẹ,y,z,u D) a,e,ẹ,i,o,ọ,u
- 8. Òpómúléró inú gbólóhùn ni_____
A) Ọ̀rọ̀ onísílébù B) Ọ̀rọ̀ àpónlé C) Ọrọ orúkọ D) Ọ̀rọ̀ ìṣe
- 9. ____ni ọ̀ro tí ó ń tọ́ka sí ìṣèlẹ̀ tàbí ohun ti ẹnìkan ṣe nínú gbólóhùn.
A) Ọ̀rọ̀ àpónlé B) Ọ̀rọ̀ àpèjúwe C) Ọ̀rọ̀ ìṣe D) Ọ̀rọ̀ arọ́pò orúkọ
- 10. 'Mo wá sùgbọ́n ń kò ba yín'. Èwo ni ọ̀rọ̀ àsopọ nínú gbólóhùn yìí?
A) yín B) sùgbón C) mo wá D) ba
- 11. ____ ni àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi ń so àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tàbí gbólóhùn pọ̀.
A) Ọ̀rọ̀ àpónlé B) Ọ̀rọ̀ atọ́kùn C) Ọ̀rọ̀ ìṣe D) Ọ̀rọ̀ àsopọ̀
- 12. ____ni egbẹ̀rún ní òǹkà Yorùbá.
A) 10,000 B) 1000 C) 5000 D) 3000
- 13. _____ni àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi ń so àwọn ọ̀rọ̀ orúkọ tàbí gbólóhùn pọ̀.
A) Ọ̀rọ̀ àsopọ B) Ọ̀rọ̀ àpọ́nlé C) Ọ̀rọ̀ àpèjúwe D) Ọ̀rọ̀ atọ́kùn
- 14. Kọ́ńsónáǹtì akọ́kọ́ nínú álífábẹ̀ẹ̀tì Yorùbá ni____
A) b B) a C) z D) d
- 15. Lẹ́tà tí ó parí álífábẹ̀ẹ̀tì Yorùbá ni___
A) i B) e C) y D) u
- 16. Álífábẹ̀ẹ̀tì Yorùbá tó wà ní ipò kárùn-ún ni____
A) ẹ B) gb C) f D) b
- 17. Wa ri mi ni Abuja. 'ni' nínú gbólóhùn yi jẹ ọ̀rọ̀____
A) iṣe B) àpọ́nlé C) atọ́kùn D) arọ́po orúkọ
- 18. Fáwẹ̀lì àkọ́kọ́ nínú álífábẹ̀ẹ̀tì Yorùbá ni____
A) ẹ B) a C) o D) i
- 19. Fáwẹ̀lì yìí kìí ṣe ti Yorùbá
A) ọ B) i C) o D) ea
- 20. "Fọláké pupa fòò". fòò nínú gbólóhùn yìí jẹ́ ọ̀rọ̀_____.
A) ẹ̀yán B) ìṣe C) àpọ́nle D) atọ́kùn
- 21. Ọ̀rọ̀-orúkọ àbọ̀ nínú gbólóhùn yìí: "Mo jẹ iyán tán" ni____
A) jẹ B) mo C) Iyan D) tan
- 22. Ọ̀rọ̀-orúkọ tí ó ṣiṣẹ́ ẹ̀yán nínú gbólóhùn yìí: "Ìyàwó Bísí wọ aṣọ òfì" ni____.
A) Bísí B) wọ C) Ìyá D) aṣọ
- 23. _____ni ọ̀rọ̀ tí ó ń tọ́ka iṣẹ tàbí ohun tí ẹnìkan ṣe nínú gbólóhùn.
A) Ọ̀rọ̀ ìṣe B) Ọ̀rọ̀ àpèjúwe C) Ọ̀rọ̀ orúkọ D) Ọ̀rọ̀ àpọ́nlẹ́
- 24. Ọ̀rọ̀_____ ni a máa n lo rọ́pò ọ̀rọ̀ orúkọ.
A) àsopọ̀ B) arọ́pò orúkọ C) ìṣe D) àpèjúwe
- 25. "Aṣọ funfun ni ìyàwó wọ̀". _____ ni ọ̀rọ̀ àpèjúwe nínú gbólóhùn yìí.
A) Funfun B) ni C) Aṣọ D) Iyawo
- 26. Abi, sùgbọ́n, pẹ̀lú,àti,àmọ́ ni àwọn àpẹẹrẹ ọ̀rọ̀_____.
A) Arọ́pò B) Àsopọ C) Àpèjúwe D) Atọ́kùn
- 27. "Délé ti Ìbàdàn dé lánàá". ____jẹ ọ̀rọ̀ atókùn nínú gbólóhùn yìí
A) lánàá B) Délé C) ti D) ni
- 28. Bí____ kò bá sí nínú gbólóhùn, gbólóhùn bi kò lè ní ìtumọ̀ kíkún.
A) ọ̀rọ̀ ìṣe B) ọ̀rọ̀ àpèjúwe C) ọ̀rọ̀ orúkọ D) ọ̀rọ̀ atọ́kùn
|