ThatQuiz Test Library Take this test now
JS 3 Ede Yoruba: 1st Term - Quiz
Contributed by: College
  • 1. 1. Parts of speech ni ede Yoruba ni
A) Ipin oro
B) Isori oro
C) Apa oro
D) Akole oro
E) Eyan oro
  • 2. 2. Preposition tumo si oro............ni ede Yoruba
A) Asopo
B) Atokun
C) Ise
D) Asapejuwe
E) Aponle
  • 3. 3. Ewo ni isare ajemayeye ninu awon oro wonyi?
A) Esa
B) Ekun iyawo
C) Ijala
D) Iyere
E) Oya pipe
  • 4. 4. Orisa wo ni won n ki pe " laalu ofiri oko"
A) Esu
B) Ogun
C) Oya
D) Sango
E) Obatala
  • 5. 5. Esin wo ni kii se esin ode oni ninu awon wonyii? Esin
A) Ibile
B) Islam
C) Kirisiteni
D) Ekànka
E) Guru
  • 6. 6. Odun wo ni awon omo leyin Jesu maa n se ninu osu kejila? Odun
A) Keresimesi
B) Tuntun
C) Ileya
D) Aawe
E) Esita
  • 7. 7. Ki ni oruko awon omo meji ti iya kan bil leekannaa ni ojo kan soso?
A) Ibeji
B) Idogbe
C) Idowu
D) Alaba
E) Ibeta
  • 8. 8. Ewo ninu awon oruko wonyii ni awon Yoruba maa n pe omo tuntun?
A) Ikoko
B) Ibeji
C) Ige
D) Apeke
E) Aadamo
  • 9. 9. Ewo ni nnkan eelo isomoloruko ni ile Yoruba ninu awon wonyii?
A) Ata
B) Igbale
C) Igi
D) Omi
E) Elubo
  • 10. 10. 600 ni onka je
A) Aadorun
B) Egberun
C) Egbefa
D) Egbewa
E) Egbeta
  • 11. 11. Aadofa ni figo je
A) 131
B) 101
C) 111
D) 1110
E) 110
  • 12. 12. Eeta le laadorun je
A) 63
B) 73
C) 83
D) 93
E) 53
  • 13. 13. Meedogun + eeta din logoji=
A) Aarun din logorin
B) Aarun din laadota
C) Eeji le laadota
D) Eeta din logbon
E) Erin le logun
  • 14. 14. Otaleerugba din marun je
A) 245
B) 235
C) 225
D) 215
E) 255
  • 15. 15. 800 je....... ni onka
A) eedegbesan
B) Eedegbeta
C) Egberin
D) Egbefa
E) Egbewa
  • 16. 16. Orin le nirinwo din marun je
A) 280
B) 420
C) 350 nirinwo
D) 520
E) 475
  • 17. 17. Igbeyawo ode oni pin si ona
A) Aimoye
B) Merin
C) Marun
D) Meta
E) Meji
  • 18. 18. Iru igbeyawo wo ni pko iyawo ko gbodo fe iyawo miran leyin asopo won gege bii oko ati iyawo? Igbeyawo
A) Soosi
B) Tiwantiwa
C) Masalaasi
D) Kootu
E) Ibile
  • 19. 19. Ilana melo ni o wa ninu Igbeyawo ibile?
A) Mejo
B) Mewa
C) Mefa
D) Mata
E) Mesan
  • 20. 20. Ninu Igbeyawo mosalasi, tani o maa n so yigi laarin oko ati iyawo?
A) Alufaa
B) Pasito
C) Baba iyawo
D) Olori ebi
E) Baba oko
  • 21. 21. Ninu asa igbeyawo ni ile Yoruba, tani o maa n san owo ori iyawo?
A) Ebi iyawo
B) Baba iyawo
C) Ore oko
D) Oko iyawo
E) Ebi oko
  • 22. 22. Ewu wo ni o lee wa, ti oko ko ba ba iyawo re nile?
A) Iyawo yoo tete loyun
B) Ibeji ni iyawo yoo maa bi
C) O lee fa ipinya laarin oko ati iyawo
D) Inu oko yoo maa dun
E) Inu iyawo yoo maa dun
  • 23. 23. Ewo ninu awon nnkan wonyii ni o maa n fi se idana ni ile Yoruba?
A) Ata
B) Owo
C) Ose
D) Kankan
E) Owu
  • 24. 24. Ti okunrin tabi obinrin ba ti dagba to eni ti o lee feyawo tabi loko ni Yoruba n pe ni
A) Gbon
B) Moye
C) Dagba
D) Laju
E) Balaga
  • 25. 25.......... ni ki omobinrin ma tii ni ibalopo kankan . titi ti yo fi lo si ile oko re
A) Amojuto
B) Itoju
C) Balaga
D) Ibale
E) Ipinnu
  • 26. 26. Gbigbe ohun ti a n ta si oju kan fun onibara lati ri, ki o si nife lati raa ni
A) Itowo oja
B) Ipalemo oja
C) Ipate oja
D) Ifihan oja
E) Atokun oja
  • 27. 27. Agbenuso laarin oko ati iyawo ni
A) Alamojuto
B) Alarena
C) Alagbaso
D) Olubadamoran
E) Agbenuso
  • 28. 28. kiko ebun lo si ile iyawo lati odo awon ebi oko ni a n pe ni
A) Iwadi
B) Isegiri leekannaa
C) Igbeyawo
D) Ijehen
E) Idana
  • 29. 29. A maa n fi ataare se adura nibi
A) Isomoloruko
B) Isinku
C) Oye jije
D) Igbeyawo
E) Odun eegun
  • 30. 30. 398 je......ni onka Yoruba
A) Aarun din nigba
B) Eeji din nirinwo
C) Eeji le nirinwo
D) Eerin le nigba
E) Aarun din loodunrun
  • 31. 31. Iru leta wo ni a n ko si oga ile ise ijoba? Leta
A) Itewa
B) Abaniwase
C) Aigbefe
D) Gbefe
E) Adako
  • 32. 32. Iru eni wo ni a lee ko leta gbefee si?
A) Oga Ile ise
B) Oga Ile eko
C) Ore
D) Oga Ile ifowopamo
E) Ile ise ijoba
  • 33. 33. Ewo ninu awon wonyii ni o lee fa airisese?
A) Itepamose
B) Akitiyan lati da si idagbasoke ilu
C) Nini Ife si owo lai sise
D) Inife si owo sise
E) Tite siwaju lori eko
  • 34. 34. Awon wo ni airisese wopo ni aarin won? Awon
A) Omode
B) Alakowe
C) Arugbo
D) Okunrin'
E) Odo
  • 35. 35. Airisese lee fa ki eniyan
A) Ma bowo fagba
B) Ma lee jeun daadaa
C) Pokunso
D) Sanra
E) Maa se ofofo
  • 36. 36. Ipolowo oja mu ki ontaja
A) Ki ere po sii
B) Ki gbese Po
C) Ki awon onibara ma ra oja mo
D) Ontaja ma ri oja ta
E) ni onibara pupo sii
  • 37. 37. Owe Yoruba so pe, " owo ti ada ba mo....... "
A) "lo je ki o sonu"
B) "lo n kaa leyin"
C) "lo n daa lagara"
D) "lo n baa je"
E) "lo n je ki o ku lenu"
  • 38. 38. Ko lo nile, kowo de, iru oja won ni maa n polowo bayii?
A) Oyin
B) Aso
C) Agbado
D) Gaari
E) Isu
  • 39. 39. Bayi ni a se maa n polowo iyan
A) Oniyan n lo ile
B) E rayan , e jeun o
C) Iyan ire, obe ire
D) Iyan ree
E) E woju obe ,e muyan
  • 40. 39. Awon oro aropo oruko wo ni o wa ninu gbolohun yii? "Mo ti ri won tipetipe"
A) Won ati tipetipe
B) Ri ati tipeipe
C) Ri ati won
D) Mo ati ti
E) Mo ati won
  • 41. 40. Ewo ni o lee sise oluwa, abo ati eyan ninu awon isori oro wonyii? Oro
A) Atokun
B) Asopo
C) Oruko
D) Aropo oruko
E) Ise
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.