ThatQuiz Test Library Take this test now
PES JS 1 Yoruba (Obj) 2nd Term Exam 2025/2026
Contributed by: School
  • 1. "Introduction " ninu aroko Yoruba ni a n pe ni
A) Akole
B) Ifaara
C) Akoto
D) Koko oro
  • 2. Igbese akoko ninu aroko kiko ni......
A) Ikadi
B) Ikini
C) Akole
D) Ifaara
  • 3. Ipin afo tumo si......
A) Introduction
B) Conclusion
C) Title
D) Paragraph
  • 4. Ohun ti a ro lokan ni ori koko oro kan ti a si ko sile ni a n pe ni......
A) Awawi
B) Akosori
C) Aroko
D) Awiye
  • 5. "Outline of points " tumo si........... ninu aroko
A) Koko oro
B) Akole
C) Igunle
D) Ilapa ero
  • 6. Ewo ni abuda aroko oniroyin ninu awon gbolohun won yii?
A) Otito ni a gbodo so ninu aroko oniroyin
B) O se pataki ki a paro mo ara wa ninu aroko oniroyin
C) A gbodo fi iro die si aroko oniroyin
D) Oro alufansa gbodo wa ninu aroko oniroyin
  • 7. Ewo ni apeere aroko oniroyin ninu awon ori oro won yii?
A) Eko ofe dara ju ekodowo lo
B) Ija igboro to soju mi
C) Oluko mi
D) Igi owo
  • 8. Ewo ninu orisii aroko won yi ni o ni adiresi ?
A) Leta kiko
B) Aroko oniroyin
C) Aroko alariyanjiyan
D) Aroko alalaye
  • 9. Leta aigbefe je leta ti a ko si.......
A) ore eni ladugbo
B) eni ti o wa nipo agbara
C) Egbon iya eni
D) Baba to bini
  • 10. Ewo ni apeere ikini ibere ninu awon won yi?
A) Egbon mi atata
B) Se alaafia ni e wa
C) Emi ni aburo re tooto
D) Inu mi dun lati ko iwe yii si yi
  • 11. Adiresi melo ni leta gbefe gbodo ni?
A) Eyo kan
B) Meji
C) Meta
D) Ko ni rara
  • 12. Eni ti a ko leta si ni a n pe ni.......
A) Akoleta
B) Apo iwe
C) Afiletaranse
D) Agbaleta
  • 13. Iyato to wa laarin leta gbefe ati leta aigbefe ni......
A) Leta gbefe ni lbuwolu, aigbefe ko
B) Leta gbefe ni ikadi, aigbefe ko ni
C) Leta gbefe ni akole, aigbefe ko ni
D) Leta gbefe ni adiresi kan, aigbefe ni meji.
  • 14. Idi ti a fi n ko leta ni lati......
A) so ohun ti a ni lokan lati so fun elomiran
B) gbe iroyin eleje
C) se ipolowo oja
D) se ikede isele
  • 15. Leta ti o gba kiko oruko kan ni soki ni ipari ni ......
A) aroko alalaye
B) leta gbefe
C) leta aigbefe
D) aroko oniroyin
  • 16. 500 ni onka Yoruba je.....
A) Eedegbeta
B) Eedegberin
C) Egberin
D) Egbeta
  • 17. Egberun ni figo je.....
A) 1000
B) 2002
C) 900
D) 2020
  • 18. 200 × 6 = ? ni onka Yoruba ni.....
A) Ogosan
B) Egbefa
C) Ogofa
D) Egbeje
  • 19. 300 + 60 = ? ni onka Yoruba je......
A) Ota le legberin
B) Ota le Oodun
C) Oji le Oodun
D) Ota le nirinwo
  • 20. (200 × 2) + 100 = ?
    Ki ni o je ni onka Yoruba?
A) Egberin
B) Eedegbeta
C) Eedegberin
D) Egbeta
  • 21. Eedegberun je.... ni onka geesi.
A) 700
B) 500
C) 900
D) 1000
  • 22. Eya Yoruba ti a le ri ni ipinle Oyo ni won yii, ayafi.....
A) Oke-ogun
B) Ibarapa
C) Onko
D) Ekiti
  • 23. Ewo ni kii se eya Egba ninu awon eya Yoruba won yii?
A) Ibadan
B) Ake
C) Abeokuta
D) Gbagura
  • 24. Ilu ninu awon ilu won yii ni ko si ni ipinle Eko?
A) Ofa
B) Oshodi
C) Agege
D) Epetedo
  • 25. Ipinle wo ni a ti le ri eya Yagba? Ipinle .......
A) Ogun
B) Kwara
C) Kogi
D) Eko
  • 26. Okere ni oruko oba ilu......
A) Okeho
B) Saki
C) Oyo
D) Ijesa
  • 27. "Deji" ni oruko oba ilu......
A) Akure
B) Ijebu igbo
C) Ile ife
D) Ifewara
  • 28. Oye oba ilu Ikorodu ni........
A) Alaafin
B) Olu
C) Ayanburen
D) Deji
  • 29. Ounje awon igbomina ni.......
A) Eko ati obe ewedu
B) Eko ati ekuru
C) Eko ati akara
D) Eko ati efo
  • 30. Ilu wo ninu awon won yii ni kii se eya ijebu?
A) Epe
B) Sagamu
C) Ikene
D) Oyo
  • 31. Ipinle wo ni a ti le ri eya ijesa
A) Eko
B) Ondo
C) Osun
D) Ekiti
  • 32. Ilu wo ni o yan iyan ati eran-oya laayo?
A) Ijebu
B) Owo
C) Egba
D) Ilorin
  • 33. Awon eya wo ni o maa n je eku?
A) Awori
B) Ijebu
C) Ondo
D) Owo
  • 34. Ikokore ati ibiripo ounje awon eya......
A) Ijesa
B) Ijebu
C) Osun
D) Ekiti
  • 35. Kaba, Egbeda, Mopa - Agbede ati Isanlu labe eya........
A) Akoko
B) Yagba
C) Ogun
D) Ondo
  • 36. Ewo ninu awon ipinle won yii ni kii se ipinle iran Yoruba? Ipinle.....
A) Oyo
B) Osun
C) Ekiti
D) Abia
  • 37. Ewo ninu awon ilu won yii ni a ti le ri iran Yoruba ni iwo oorun Afirika?
A) Ile Antatika
B) Ile Indian
C) Ile Amerika
D) Ile olominira Saro
  • 38. Ibi ti a tun ti le ri iran Yoruba ni orile ede agbaye ni......
A) Gambia
B) Russian
C) Zimbabwe
D) Brazil
  • 39. Iran omo Yoruba ni o je oba ni orile ede Olominira Bini?
A) Oba Ibini
B) Osemawe Atewogbeja
C) Obasakin
  • 40. Ki ni oye oba Ile Ife?
A) Esubeleke
B) Osemawe
C) Ooni
D) Alaafin
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.