ThatQuiz Test Library Take this test now
AIC Yoruba 1st Term Exam for JS 3
Contributed by: College
  • 1. 2000 ní òǹkà Yorùbá ni___
A) Ẹgbàá rin
B) Ẹgbẹrun
C) Ogún
D) Ẹgbàá
  • 2. Kí ni 20,000 ní òǹkà Yorùbá?
A) Ẹgbarun
B) Ẹgbàafà
C) Ẹgbàá je
D) Ẹgbàá wà
  • 3. Ohun tí kò tọ́ tí a ṣe sí ọmọlàkejì ni ìwà___
A) Ọ̀sì
B) Ìdọ̀tí
C) Ìkà
D) Omolúàbí
  • 4. Ìwọ̀nyí ni ìwà ìkà tí ó wọ́pọ̀ ni ayé àtijọ́ àyàfi___
A) Ìfiniṣẹrú
B) Ìfiniṣọfà
C) Ìfọmọṣowó
D) Ìfinirúbọ
  • 5. Ìwà ìkà tí o wọ́pọ̀ lóde òní ni ìwọ̀nyí, àyàfi___
A) Lílo ọmọ nílọ̀kulọ̀
B) Ìfiniṣọfà
C) Ìjínigbé
D) Ìfiniṣowó
  • 6. Ọ̀rọ̀____lè ṣiṣẹ́ olùwà,ẹ̀yán, àti àbọ̀.
A) Orúkọ
B) àpèjúwe
C) ìṣẹ
D) àpónlé
  • 7. ____ ni àwọn Yorùbá gbà pé wọ́n ń sọ ọjà di ọ̀wọ́n.
A) Alágbàtà
B) Ọlójà
C) Oníbárà
D) Èrò ọjà
  • 8. À n ṣe òwò kí á le____
A) jẹ èrè
B) ríhun ṣe
C) di ìyálọ́jà
D) sọ́ọ̀tì
  • 9. Àǹfààní òwò ṣiṣe níwònyí àyàfi; Ó ń mú ____
A) kí ìṣẹ́ àti òṣì pòórá
B) ẹni di ọ̀lẹ
C) kí a níṣẹ́ ẹni lọ́wọ́
D) kí a tẹpá mọ́ṣẹ́
  • 10. ____tàbí káràkátà jẹ́ ọ̀kan nínú ara iṣẹ owó Yoruba.
A) Aróbọ̀
B) Oúnjẹ jíjẹ
C) Ìwà òtítọ́
D) Òwò ṣíṣe
  • 11. Ẹni tí ó ta ọjà tí kò jèrè ni won ní o____
A) gbìyànjú
B) ṣòwò sọ́ọ̀ti
C) tẹpá mọ́ṣẹ́
D) tàtà jèrè
  • 12. Ìwòyí ni iṣẹ tí ọ̀rọ̀ orúkọ le ṣe,ayafi____
A) òpómúléró
B) ẹ̀yán
C) olùwà
D) àbọ̀
  • 13. 'Bàbá Bọ́lá lọ sí oko'. Kí ni ọrọ orúkọ tí o se iṣẹ́ ẹ̀yán nínú gbólóhùn yìí?
A) Bọ́lá
B) Oko
C) lọ
D) Bàbá
  • 14. Èwo ni kìí ṣe álífábẹ̀ẹ̀tì ede Yorùbá
A) ae
B) o
C) a
D) b
  • 15. Àmì Ohùn òkè ni___
A) _
B) -
C) \
D) /
  • 16. Àmì wo ni ó bá ọ̀rọ̀ yí mu? kirakita--d:d:d:d
A) Kìràkìtà
B) Kìrákítà
C) kirakitā
D) kirákíta
  • 17. Àmì wo ni ó bá ọ̀rọ̀ yí mu? Dodo--d:d
A) Dòdò
B) Dodo
C) Dódó
D) Dọ̀dó
  • 18. Fáwẹ̀lì Yorùbá pín sí:
A) àìránmúpè ati àrańmúpè
B) arẹ́họ́n ati àkùnyùn
C) àìgbẹ̀fẹ̀ àti agbẹ̀fẹ̀
D) àfúnupè àti aṣẹ́nupè
  • 19. Tọ́ka sí ọ̀rọ̀-orúkọ olùwà nínú gbólóhùn yìí: "Ajá bàbá Olú tí jẹ ẹja náà"
A) bàbá
B) náà
C) Olú
D) Ajá
  • 20. "Ojó lọ ra ẹja tí yóò jẹ" Tọ́ka sí ọ̀rọ̀-orúkọ àbọ̀ nínú gbólóhùn yìí.
A) ẹja
B) ra
C) Ojo
D) lọ
  • 21. "Adébísí pa ẹran màálu jẹ". Èwo ni ọ̀rọ̀-orúkọ tí ó ṣiṣé ẹ̀yán nínú gbólóhùn yìí?
A) pa
B) Adébísí
C) màálu
D) ẹran
  • 22. Kí a tó lè di oníṣòwò,a gbọ́dọ̀ ní nǹkan wọnyí àyàfi____.
A) ìdọmọ ẹgbẹ́ ọlọ́jà
B) ní ìmọ̀ nípa ọjà ta fẹ tà
C) owó òkòwò
D) ẹ̀kọ́sẹ́ kátà-kárà
  • 23. Fífún òǹràjà ní díẹ̀ jẹ nínú ọjà tí à ń tà ni à ń pè ní_____.
A) ènì
B) sàn díẹ̀díẹ̀
C) àwín
D) ìtọ́wọ̀
  • 24. Ìwọ̀nyí ni àwọn owó tí a mọ àwọn Yorùbá sì àyàfi_____.
A) Aṣọ títa
B) Aróbọ̀
C) Ìjínigbé
D) Owóróbo
  • 25. ______ni à ń pe àwọn tí n ta ọjà pẹ́ẹ́pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ́.
A) Oníwóróbo
B) Aláróbò
C) Alájàpá
D) Olóúnjẹ
  • 26. Ọ̀rọ̀ orúkọ inú gbólóhùn yìí "Motúnráyọ̀ sì tún rápálá wọlé" ni:
A) Motúnráyọ̀
B) si
C) tun
D) wọlé
  • 27. Kọ́ńsónáǹtì tó wà nínú èdè Yorùbá jẹ_____
A) 17
B) 10
C) 9
D) 18
  • 28. Èwo ni kọ́ńsónáǹtì tí a fi èjì ètè pè nínú àwọn wọ̀nyí?
A) b
B) d
C) g
D) f
  • 29. ___jẹ́ fáwẹ̀lì àyanupẹ̀
A) m
B) n
C) a
D) u
  • 30. ___jẹ kọ́ńsónáǹtì àrańmúpè.
A) p
B) n
C) t
D) s
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the site for test creation and grading in math and other subjects.