ThatQuiz Test Library Take this test now
AIC JS 1 Yoruba 3rd C.A for 2nd Term - Quiz
Contributed by: College
  • 1. 106 ni onka Yoruuba ni
A) eerin din logun
B) eerin din logorun
C) eefa le logorun
  • 2. okooleerugba din mew ani
A) 220
B) 320
C) 210
  • 3. melo ni faweeli airanmupe ti o wa ninu alifabeeti ede Yoruba?
A) meje
B) mejo
C) mesan
  • 4. . Odun wo ni awon igbimo ede fi owo si lilo akotoYoruba ?
A) 1973
B) 1972
C) 1974
  • 5. kini igbese akoko ninu leta kiko? kiko
A) adiresi
B) oruko akoleta
C) deeti
  • 6. .Ewo ni akoto ode oni fun gbolohun “ Lailai”
A) leaalea
B) laelae
C) lailai
  • 7. . Konsonanti melo ni o wa ninu gbolohun ‘’ogedengbe ’’
A) 6
B) 5
C) 4
  • 8. Ewo ninu awon eniyan wonyii ni a lee ko leta gbefe si
A) egbon baba
B) alaga ijoba
C) oga ile ise
  • 9. Ninu ami ohun ni ede Yoruba, ewo ni ami isale ?
A) mi
B) do
C) re
  • 10. Leta gbefe ni a n pe ni ………………… ni ede geesi
A) informal letter
B) semi-formal letter
C) formal letter
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.