PES Yoruba JS 2 Term 1 Test 3
- 1. Eedegbeta ni figo je....
A) 600 B) 500 C) 800
A) Ota leerugba din mewa B) Ota din nigba C) Ota le loodun D) Ota din nigba le mewa
- 3. 25 + 46 = ? Kin ni esi aropo awon figo yii ni onka Yoruba?
A) Ookan din laadorin B) Ookan le laadorin C) Ookan le logorin
- 4. Onise wo ni a n ki ni " Aredu o"?
A) Akope B) Alaro C) Alagbede
- 5. Bawo ni a se n ki awako?
A) Aroko bodunde o B) Awaye o C) Aroye o
- 6. Bawo ni a se n ki eni ti o sese bimo tuntun ni ile Yoruba?
A) E ku ijade oni o B) E ku owo lomi o C) E ku oju lona o
- 7. Iru orin wo ni eyi-
" ile oko ya, Ile oko ya, Keleda iya re sin o lo Ile oko ya". Orin
A) Isile B) Amuseya C) Igbeyawo
- 8. Ewo ni kii se orisii orin ninu awon won yii?
A) Orin eremode B) Orin ijala C) Orin onka
- 9. Ohun pipe ti awon baba-nla wa n lo nibi ayeye ti ko jemo esin orisa tabi eyi ti won n ko nibi ti won n ti n bo orisa kan ni a n pe ni........
A) Isare B) Iyere ifa C) Arangbo
- 10. Ewo ninu awon won ni kii se isare Ajemesin?
A) Arungbo B) Ijala C) Rara
- 11. Awon ilu wo ni o maa n su ekun iyawo?
A) Egbs B) Ondo C) Oyo
- 12. Awon...... ni o n sun iyere ifa
A) Olosun B) babalowo C) Onisango
- 13. Ewo ni kii se ohun eelo fun orin ifa ninu awon nnkan won yii?
A) Agogo B) Ilu agere C) Obi
- 14. Won maa n pe ESA nigba ti won maa n ..... Ijala
A) sun B) so C) wi
- 15. Tani olori awon elesin Sango?
A) Adosu B) Babalowo C) Abore
- 16. Iru ilu wo ni awon onisango maa n lu ti won ba n sodun won?
A) Ilu dundun B) Ilu bembe C) Ilu bata
- 17. Awon wo ni o ni o maa n pe Esu? Awon
A) Aworo B) Olosun C) Onifa
- 19. Ewo ninu awon won yii ni eewo orisa Esu?
A) obi ati epo B) Adi ati omi C) Adi ati obi
- 20. Ewo ninu awon orisa won yii ni obinrin ko gbodo ri?
A) Oro B) Sango C) Egungun
|
Students who took this test also took :