ThatQuiz Test Library Take this test now
PES Ede Yoruba JS 1 3rd Term 3rd Test
Contributed by: School
  • 1. Ege oro ti eemi le gbe jade leekan soso ni.........
A) silebu
B) aalo
C) gbolohun
D) itan
  • 2. Kin ni ami ihun silebu yii duro fun: KF ? Apapo.......
A) Konsonanti+ Akoto
B) Konsonanti+ Silebu
C) Konsonanti+ Ami ohun
D) Konsonanti+ Faweeli
  • 3. Ewo ni oro onihun silebu kan ninu awon won yii?
A) ran
B) iya
C) omo
D) baba
  • 4. Ewo ninu awon won yii ni oro oruko ti a seda ni ilana apetunpe ?
A) Aisan
B) Panapana
C) Ijekuje
D) Ainilari
  • 5. Oro oruko wo ni a seda re pelu 'oni' ninu awon won yii?
A) oloja
B) ounje
C) oungbe
D) aheje
  • 6. Bawo ni a se seda " ilekile"?
A) ileki + ile
B) ile + kile
C) ile + ki + ile
D) ile + ko+ ile
  • 7. Ewo ni oruko ti a ko le seda ninu awon won yii?
A) Ade
B) aisun
C) Ori
D) Alata
  • 8. Irinwo ni onka ede geesi ni....
A) 1600
B) 300
C) 400
D) 200
  • 9. 200+40 je.... ni onka yoruba
A) okoo leerugba
B) ota le niriwo
C) oji leerugba
D) orin laadorin
  • 10. Ohun akoko ti a ni lati ko bi a ba n ko aroko ni......
A) Ipin afo
B) Akole
C) Koko oro
D) Ifaara
  • 11. "Introduction " ninu aroko ni
A) Ipin afo
B) ilapa ero
C) ifaara
D) greeting
  • 12. .... .... ni o n toka si isele inu aroko
A) Ilapa ero
B) Ifaara
C) Ipin afo
D) Koko oro
  • 13. Aroko oniroyin je iroyin ohun ti
A) yoo waye lola
B) a ko gbo ri
C) a ko mo nipa re
D) o sele loju wa
  • 14. Awon won yii ba abuda aroko oniroyin mu, ayafi
A) Iwon ibi ti a ri mo ni ki a so mo
B) A gbodo so otito die, ki a si fi iro pupo kun un
C) Otito ni a gbodo so
D) A ko gbodo paro
  • 15. Idi ti a fi n ko leta ni, lati
A) kede ohun tuntun ti o fe sele nile wa
B) le fi ri oro so
C) je omo rere fun eni ti a ko leta si
D) So ohun ti a ni lokan fun elomiran
  • 16. Leta gbefe ni leta ti a ko si
A) alaga ile ise ijoba
B) obi eni
C) lati fi wa ise
D) lati fi toro aaye nibi ise
  • 17. Ibo ni deeti maa n wa ninu leta?
A) Ni egbe oruko akoleta
B) Ninu koko oro
C) Abe adiresi akoleta
D) Leyin ikini ibere
  • 18. Eni ti o ko leta ni a n pe ni..... .
A) Alajako
B) Akoleta
C) Afiweranse
D) Agbaleta
  • 19. Ewo ni igbese ti ko si ninu leta aigbefe? Kiko
A) adiresi meji
B) Ibuwolu
C) adiresi kan
D) Akole
  • 20. Leta to gba oruko kan ni leta.......
A) gbefe
B) aigbefe
C) aponle
D) pajawiri
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.