ThatQuiz Test Library Take this test now
JSS2 YORUBA 3RD TERM EXAM
Contributed by: College
  • 1. _________ ni itunmo ede kan si omiran
A) Aayan ogbufo
B) Isunki
C) Ibanisoro
D) Iranra eni lowo
  • 2. Eni ti o n tumo ede kan si omiran ni a n pe ni
A) Alalaye
B) Alaroye
C) Ogbufo
D) Elejo
  • 3. E ni fe tunmo oro gbodo____
A) Lowo
B) Gbo ede mejeeji daradara
C) Lohun
D) Buru
  • 4. Ni nu aayan ogbufo,a gbodo fun oro ni
A) Itunmo ti o tobi
B) Itunmo ti o bamu
C) Itunmo ti o jin na si
D) Itunmo ti ko ye rara
  • 5. Itunmo 'Boundary' ni
A) Ile
B) Aala
C) Ise
D) Ibikan
  • 6. Itunmo 'Culture' ni
A) Aaye
B) Iwa
C) Esin
D) Asa
  • 7. Itunmo 'overlap' ni
A) Ge ara won
B) Bu ara won
C) Wonu ara won
D) Na ara won
  • 8. 'He was ashamed' tunmo si
A) Oju n dun
B) Oju tii
C) Oju e ri
D) Won doju ti
  • 9. ________ ni a fi n ke ' Ewi'
A) Oju
B) Imu
C) Emi
D) Enu
  • 10. A ma n lo 'Ewi' nibi ________
A) Ija
B) Oro aje
C) Ayeye
D) Ogun
  • 11. Ki aranmo to le wa ye,_______
A) Ko gbodo si faweeli ninu oro na
B) Konsonanti meji gbodo te le ara won
C) Faweeli meji gbodo te le ara won
D) Faweeli ko gbodo bere oro na
  • 12. Se isunki oro yii : ile + iwe
A) Ileiwe
B) Ilewe
C) Iluwe
D) Ilewe
  • 13. Gba + ise
A) Gbaise
B) Gbese
C) Gbase
D) Gbise
  • 14. Ninu ewi "ise logun ise" Ohun ti a ba fara sise fun________
A) Ni se iku pani
B) Ni pe lowo eni
C) Ni fi iya je ni
D) Ni so nu lowo eni
  • 15. Apa lara ________
A) Igunpa la ko mo
B) Igunpa ni iyekan
C) Orunkun la ba mo
D) Ori la ba bo
  • 16. Eko n so ni di_______
A) Opuro
B) Omose
C) Janduku
D) Oga
  • 17. Iro ti o ni agbara lati yi iro miran pada si tire ni________
A) Iro afaranmo
B) Aranmo aforu
C) Aranmo kikun
D) Iro agbaranmo
  • 18. Iro ti o yi pada gba abuda iro miran ni
A) Isunki
B) Iparoje
C) Iro afaranmo
D) Iro agbaramo
  • 19. Omobinrin ti o gbe ibi korun ni_____
A) Eli
B) Ayan
C) Ibikunle
D) Aina
  • 20. Omo ti iya re ko se nkan osu ti won fi bi ni
A) Ojo
B) Ilori
C) Odun
D) Dada
  • 21. Omo ti oyun re ju osu mesan lo ti won fi bi ni
A) Ajayi
B) Oke
C) Ige
D) Omope
  • 22. Omo ti o yi ara mo inu apo ni
A) Odu
B) Ige
C) Ola
D) Oke
  • 23. Apeere oruko idile "Onilu" ni
A) Ayangbade
B) Ogungbemi
C) Olalomi
D) Osuntoke
  • 24. Apeere oruko amu torunwa ni
A) Kehinde
B) Omoyeni
C) Lamidi
D) Gbemisola
  • 25. Apeere oruko Abiku ni
A) Ige
B) Idowu
C) Tope
D) Malomo
  • 26. Apeere oriki ni
A) Omotunde
B) Odun
C) Ojo
D) Alabi
  • 27. ________ wa ninu awon eelo isomoloruko
A) Alubose
B) Omitutu
C) Omigbona
D) Ororo
  • 28. Ni aye atijo ojo ___ ni a maa n so omobirin loruko
A) Keje
B) Kewa
C) Kejo
D) Kesan
  • 29. Ni aye atijo, awon okunrin ni won ma n so loruko ni ojo
A) Keje
B) Kesan
C) Keta
D) Kejo
  • 30. Ninu ewi "iwulo eko" Iwulo eko ju_________ lo
A) Orun si sun lo
B) Ile kiko
C) Oja ti ta lo
D) Omo bibi lo
  • 31. Eko n so ni di
A) Ilumoka laye
B) Jagidijagan
C) Olosi
D) Eni yepere
  • 32. Iwa ika tunmo si
A) Iwa buburu
B) Iwa alalubarika
C) Iwa igberaga
D) Iwa afojudi
  • 33. Lara iwa ika ni
A) Ere idaraya
B) Eko kiko
C) Ikonileru
D) Egbe alafowosowopo
  • 34. A le dekun iwa ibaje
A) Ti a ba bi omo pupo
B) Ti a ba lowo lowo
C) Ti a ba fi ara wa si ipo omo lakeji
D) Ti a ba fe iyawo pupo
  • 35. _________ nia fi n so oro meji papo ninu gbolohun
A) Oro aropo oruko
B) Oro asopo
C) Oro ise
D) Oro atokun
  • 36. Apeere oro atokun ni
A) Olu
B) Iwo
C) Sun
D) Si
  • 37. Apeere oro - ise ni
A) Awon
B) Ati
C) Fiofio
D) Dide
  • 38. Apeere oro - oruko ni
A) Ati
B) Emi
C) Ibadan
D) Sugbon
  • 39. Dudu gidigidi"je
A) Oro oruko
B) Oro apejuwe
C) Oro atokum
D) Oro ise
  • 40. Silebu melo lowa ninu oro wonyii "0luponmita"
A) Marun
B) Merii7
C) Mefa
D) Mee
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — the math test generation site with resources for other subject areas.