ThatQuiz Test Library Take this test now
Yoruba jss2 second term exam
Contributed by: College
  • 1. Ninu ewi " ikanju" ikanju àti _________, ògbòògba ni se
A) Ariwo
B) Ija
C) Wahala
D) Pele
  • 2. E so Pele ni _________ gba
A) Oorun
B) Ariwo
C) Aye
D) Ounje
  • 3. Pa ri oro yìí," " isé síse bí eru , ________
A) N pani
B) Ko la ni
C) N so ni di olowo
D) Fun ni alaafia
  • 4. Akewi ni kí akẹẹkọ ma se Suuru, ki o ma ba ___________,
A) Se déédéé pankere jije
B) Ki inu re le dun
C) Ki o lẹ bá gbá maaki rẹpẹtẹ
D) So òwò nu
  • 5. Kìràkìtà o ________
A) Lewu
B) Mola
C) O dara
D) Mo alejo
  • 6. Ninu "ewì ipanle"ipata ọmọ kii
A) Dagba
B) Lagbara
C) Ni iyawo
D) Tete rowo mu laye
  • 7. Ipata ọmọ tó pẹ láyé, _________ lowa
A) Oko
B) Oke okun
C) Ewon
D) Ile
  • 8. Pari oro yìí, "ọmọ lile ronú e wo, _________________
A) Ko o ma ba kabamo
B) Ki inu re le dun
C) Ki o lẹ di gbajumo
D) Ki o lẹ di olowo laye
  • 9. __________, lere ipanle
A) Ounje pupo
B) Ofo
C) Owo
D) Ipo giga
  • 10. "Pokii" tunmọ sii
A) Oloselu
B) Oluko
C) Agbalagba
D) E ni ti ìya ti yi mo lara
  • 11. "Iro" tunmọ sí
A) Ọmọ iya
B) Onisowo
C) Ẹgbẹ
D) Ará orílè-èdè
  • 12. Ere ti a ma n se lẹyin isẹ ọjọ wa ni
A) Ere ija
B) Ere takasufe
C) Ere kanpakanpa
D) Ere idaraya
  • 13. Apere ere ìdárayá ni iwọnyi ayafi
A) Ere ijakadi
B) Ere oṣupa
C) Ere bojuboju
D) Ere gbetigbeti
  • 14. Ọkan lára ipa ti orin kó nínu ere idaraya ni
A) Ebu bibu
B) Ẹkọ asa
C) Ole
D) Eke sise
  • 15. Pa ri owe yii, "ile la wo,_________",
A) Ki a to gbe omo
B) Ki a to Lu omo
C) Ki a to bimo
D) Ki a to ṣọmọ loruko
  • 16. Àwon nkan ti a man wo fun Omo loruko ni iwonyi , aya fi
A) Ise
B) Ipo
C) Ile
D) Aso
  • 17. "Yetunde " je apeere oruko
A) Abiso
B) Oriki
C) Amutorunwa
D) Inagije
  • 18. Taye àti kehinde je oruko
A) Asopo
B) Oriki
C) Abiso
D) Amutorunwa
  • 19. Ìdòwú je oruko ọmọ ti ọ tẹlẹ
A) Ige
B) Alaba
C) Ojo
D) Ibeji
  • 20. Eta oko ni ọmọ
A) Inu igi
B) Ti A bi sè iketa ibeji
C) Ti o tele ojo
D) Orí omi
  • 21. Ọmọ ti o wetabi ẹsẹ ni
A) Ojo
B) Abiona
C) Erinle
D) Olugbodi
  • 22. Ọmọ ti o dójú bọlé ni
A) Odu
B) Amope
C) ilori
D) Ajayi
  • 23. Ọmọ ti o yí ra mọ apo ni
A) Ilori
B) Oke
C) Odu
D) Ola
  • 24. Ọmọ ti ìya rè ko se nkan osu ti wọn fí bi ni
A) Yewande
B) Aina
C) Ilori
D) Iyabo
  • 25. Ewo ni kii se oruko oriki nínú iwonyii
A) Adio
B) Ajao
C) Ajayi
D) Akanji
  • 26. Àpẹẹrẹ oruko abiku ni iwọnyi ayafi
A) Bamiji
B) Bamidele
C) Banjoko
D) Bantale
  • 27. E wo ni oruko ìdílé onilu nínú iwonyii
A) Ayanwale
B) Okewale
C) Olawale
D) Adewale
  • 28. E wo ni oruko ìdílé eleegun nínú àwon oruko wonyi
A) Olorode
B) Ifabunmi
C) Ojelade
D) Ogunyemi
  • 29. Osù + oṣù =
A) Osousu
B) Osoosu
C) Osuusu
D) Osuosu
  • 30. Osan +Osan
A) Osonson
B) Osansan
C) Osunsun
D) Osoosan
  • 31. Pe eja + pe eja
A) Peejapeeja
B) Pajápajá
C) Pejaapejaa
D) Pejapeja
Students who took this test also took :

Created with That Quiz — where test making and test taking are made easy for math and other subject areas.